Paid Sick Leave - Yoruba

Labẹ New York City’s Earned Sick Time Act (Paid Sick Leave Law), (ofin Ifunni lowo Aisan ti Ilu New York (Ofin Owo Isinmi Aisan), awọn oṣiṣẹ ti o wa labẹ eyi ni anfaani lati lo isinmi aisan fun ibojuto ati itọju ara ọn tabi ti ẹbi wọn.

AKIYESI ẸTỌ OṢIṢẸ (Notice of Employee Rights in PDF)

OWÓ ÌSINMI ÀÌSÀN: TI OṢIṢẸ GBỌDỌ MỌ (Paid Sick Leave Law: What Employees Need to Know in PDF)

OWÓ ÌSINMI ÀÌSÀN: OHUN TI AGBANISIṢẸ GBỌDỌ MỌ (Paid Sick Leave Law: What Employers Need to Know in PDF)